Díẹ̀kọ́lá fa Akin mọ́ra pẹ̀lú agbára, àwọn méjèjì ti bẹ̀rẹ̀ sí lọ́ ètè ara wọn jẹ bi pọ̀mọ́ aláta súẹ́súẹ́. Nígbà tí Díẹ̀kọ́lá wọ inú 'ọ́fìsì' yẹn wá lẹ́ẹ̀kan, ó ti t'ilẹ̀kùn pa. Bí ẹnikẹni yóò bá wọlè, wọn á kan ilẹ̀kùn. Bí ètè jíjẹ ti ń wọra,
bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ń sún láti ibi kan sii èkejì nínú 'ọ́fìsì' Akin. Síbẹ̀, iṣẹ́ ẹ́nú àti ahọ́n ń lọ ní rẹ́surẹ́su. Bí wọ́n ti sún sí orí àga kan báyìí, ni àwọn méjèjì bá bẹ̀rẹ̀ sí gba aṣọ kúrò ní ara wọn. Bí ẹni kíni ti ń sáré bọ́ ti èkejì, ni èkejì náà ń ṣe
bàlàbàlà gba ti ara ìkíní. Wọ́n ń wọ ìdìmú ara bí ẹ́ni tí wèrèpè kán lù. 'Súùtí' tí Akin wọ̀ rèé ní orí 'rọ́ọ̀gì', 'sẹ́ẹ̀tì' náà ń serè ní etí àga. Gbogbo ohun tí Díẹ̀kọ́lá náà tò mọ́ ara ti wá ibi gba.
Eré àníyàn fẹ́ ma wọra nínú 'ọ́fìsì' Akin. Ó ti ku ṣòkòtò
lásán ní ìdí Akin, ni Díẹ̀kọ́lá náà bá nawọ́ lọ síbi kiní ìsàlẹ̀ Akin. Ara Akin ta gìrì. Gbogbo iṣan ara rẹ̀ ń díde, orí rẹ̀ ti bẹ̀rẹ̀ sí hó bí o ti ń jẹ ètè, tí ara ibí sì ń tú 'síìbù' ṣòkòtò mọ ní ìdí. Díẹ̀kọ́lá ṣe bẹ́ẹ̀, ó tú ṣòkòtò ní ìdí Akin, síbẹ̀,
wọn ò dá eré dúró. Àwọn méjèèjì ti jọ gba aṣọ kúrò ní ara, iná ń jó, wọn ń fẹ́ pẹ́lù eré àníyàn wọn. Ara ń kan ara, wọ́n họ àágùn yọ̀bọ̀, iṣan oníkálukú ló ń díde ní ìsẹ́jú kan sí ìkejì.
Níbi tí eré dé yìí, Díẹ̀kọ́lá tún mú ọwọ́ padà lọ síbi kinì Akin, ìyẹn náà ti dúró dédé bíi àwọn kúlíkúlí gbọrọ tí wọ́n tà ní Bódìjà. Bó ti bẹ̀rẹ̀ sí fi ọwọ́ raá síwájú sẹ́yìn, ni Akin ń gbin bíi ẹni tí wọ́n ń fi ìyẹ́ adìrẹ rìn ní inú etí.
Bí Akin ti ń ṣe ojú, ó fi dá Díẹ̀kọ́lá lójú pé, òhun gbádùn iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀. Kí a má tún fa ọ̀rọ̀ gún, Díẹ̀kọ́lá tún ń ṣe kàbàkàbà sún sí orí ìkúnlẹ̀, Akin ń wò ó ní orí ìdúró tí òhun wà. Ó ń rẹ́rìín músẹ́ bí Díẹ̀kọ́lá ti ń gbé kiní rẹ̀ lọ sí ọ̀nà ẹnu.
Ẹni tí Èṣù yóò ṣe, èwọ̀ ni yóò kọ́kọ́ jẹ. Láì b’èsù b’ẹ̀gbà, Akin àti Díẹ̀kọ́lá ṣe bẹ́ ẹ̀ ní àjọṣepọ̀ nínú ilé iṣẹ́ náà. Ní abẹ́ ìsẹ́jú mẹ́tàdínlọ́gbọ̀n, eré àníyàn ti re ibi àná, oníkálukú wọ́n ti padà sí ẹnu iṣẹ́ rẹ̀ láì fu ẹnikẹni lára.
Gbogbo bí ọ̀rọ̀ ti lọ láàárín Akin àti Díẹ̀kọ́lá ní bíi oṣù kan sẹ́yìn ni Akin ń rántí ní orí ìdúró tí ó takú sí, bíi òpó iná nínú ilé ìtura kan báyìí tí ó wà ní ọ̀nà Àpáta. Díẹ̀kọ́là tó já gudugbẹ̀ ọ̀rọ̀ sílẹ̀ rè é lórí tìmùtìmù tí ó fi ìkàlẹ̀ sí.
Ikún ń jẹ ọ̀gẹ̀dẹ̀ ikún ń rè ìdí, ikún ò mọ̀ pé ohun tó dùn ń pani. A dífá fún Akin tí í se ọ̀gá fún Díẹ̀kọ́lá ní ilé iṣẹ́ ńlá kan ní ojú ọ̀nà Ring Road, Ìbàdàn.
Complete the story when you purchase Ajíláàláọ̀ṣọ́ at paystack.com/buy/ajilaalaoso
Share this Scrolly Tale with your friends.
A Scrolly Tale is a new way to read Twitter threads with a more visually immersive experience.
Discover more beautiful Scrolly Tales like this.
