YorubaNewsAlert Profile picture
Alert on Yoruba News! Àwa kò pe arawa ní Ògbólógbòó ọ̀mọ̀ràn èdè Yorùbá rárá o. Breaking News–Politics! Arts! Culture! Alamojuto: Ogbeni Olu Josefu ati Oladuni
Nov 13, 2018 18 tweets 9 min read
Ila ọ̀rọ̀ Ipolongo Àwọn alaye ohun tí @MBuhari ati @ProfOsinbajo tí ṣe láti ọdún merin seyin nílè Yorùbá👇👇 1. Ilé igbe olówó pooku ìjọba àpapọ̀ ni Abeokuta Ipinle Ogun.
Ìjọba àpapọ̀ ńkọ ilé ìgbé́ àádọ́jọ sí ìlú Àkúré, Òndó pẹ̀lú ìrànwọ́ ajo tó ṣe onigbowo ikole ni Nàìjíríà (NHF).