Profile picture
YorubaNewsAlert @YorubaNewsAlert
, 18 tweets, 9 min read Read on Twitter
Ila ọ̀rọ̀ Ipolongo Àwọn alaye ohun tí @MBuhari ati @ProfOsinbajo tí ṣe láti ọdún merin seyin nílè Yorùbá👇👇
1. Ilé igbe olówó pooku ìjọba àpapọ̀ ni Abeokuta Ipinle Ogun.
Ìjọba àpapọ̀ ńkọ ilé ìgbé́ àádọ́jọ sí ìlú Àkúré, Òndó pẹ̀lú ìrànwọ́ ajo tó ṣe onigbowo ikole ni Nàìjíríà (NHF).
2. @MBuhari ato @ProfOsinbajo se Eto ikole gbogboogo ijoba tó ń lọ lọ́wọ́ ni ilu Ibadan, ìpínlè Ọ̀yọ́ tí pèsè ìṣe ẹgbẹ̀rún merin lé laadorin fún àwọn ọmọ Nàìjíríà ni agbègbè náà.
3. Eto ikole gbogboogo ijoba apapo yìí bákan náà tó ń lọ lọ́wọ́ ni Abere, Ìpínlẹ̀ Ọsun ti kú ìṣẹ́ perete tí yóò fi parí.
ÀKÀNṢE IṢẸ́ OJÚ PÓPÓ tí @MBuhari ati @ProfOsinbajo tí ṣe láti ọdún merin seyin nílè Yorùbá

1. Òpópónà marose Oyo-Ogbomoso ti wọn n fi owó Sukuk ṣe, àtúnṣe òpópónà Ilorin-Jebba - Mokwato tí di apati láti nkan bíi odun mẹ́wàá sẹ́yìn,
2. Òpópónà marose Lagos - Ibadan náà tí de ìdajì nínú ṣíṣe rẹ tí sì ti pèsè isẹ to dín di ẹni ẹgbẹ̀rún márùn-ún fún agbase ṣe àti àwọn olodani.
3. Ìjọba àpapọ̀ @MBuhari @ProfOsinbajo yóò parí òpópónà Gbongan - Iwo tó dín díè ni bilionu méje náírà àti afárá ojutu ẹlẹ́dẹ̀ẹ́gbeta lè mejidinlogoji mílíọ̀nù náírà ni Ilobu nipinle Ọsun.
4. Òpópónà òní kìlómítà marun-un lè lọgbọn Tin Can Island - Mile two- Oshodi ti wa lọ́wọ́ ilé iṣé Dangote gege bíi kongila to ń ṣíṣe náà, òpópónà òní títì mẹ́wàá ni wọn ń pínu láti fi kankere ko.
Àwọn alaye ohun tí @MBuhari ati @ProfOsinbajo tí ṣe

ETO OGBIN.

1. Nígbà tí ọdún 2017 dá di méjì, O kéré tán àwọn agbe tó ń sìn adìye bíi egberun mẹ́wàá lọ gba adìye Osin ọgọrun kọ̀ọ̀kan lábé ètò Anchor Borrower tí CBN sagbekale rẹ ni ìpínlè Eko
2. Ìjọba àpapọ̀ @MBuhari @ProfOsinbajo tún fún àwọn àgbè FADAMA ni mílíọ̀nù kan náírà ni ìpínlè Ondo lọ́dún 2017
Ila ọ̀rọ̀ Ipolongo Àwọn alaye ohun tí @MBuhari ati @ProfOsinbajo tí ṣe láti ọdún merin seyin nílè Yorùbá👇👇

IDOKOOWO

1. Igbakeji ààrẹ Yemi @ProfOsinbajo sabewo sì Silicon Valley àti Nollywood láti mú iwuri bá àwọn oludokoowo aladani láti wá sí orile-ede Naijiria.
2. Trader Moni tí igbakeji ààrẹ @ProfOsinbajo tún ṣe agbaterun rẹ náà tún ń mú adinku bá ainiselowo nítorí eto naa fún òpó láǹfààní láti bẹ̀rẹ̀ oko-owo ara wọn.
ÒṢÈLÚ IWO-OORUN - GÚÚSÙ Àwon ènìyàn ẹkùn ìwọ-oòrùn-gúúsù ni opo ìgbà kii sáábà darade ijoba apapo fún ohunkóhun bí àwọn ẹkùn toku ṣe máa ń ṣe, sugbon lọ́dún 2015, ifowosowopo wọn ṣe àmújáde igbakeji ààrẹ láti ìwọ-oòrùn-gúúsù @ProfOsinbajo fún ìgbà àkọ́kọ́ lodun 2015
Ọ̀pọ̀ àwọn minisita tó wà láti ìwọ-oòrùn-gúúsù leyin ti wọn fimoṣọ̀kan tó fi mọ àwọn asoju orílẹ̀ èdè, àwon Oga ilé iṣé ni wọn yàn lai fi teya ṣe.
Ọkàn nínú irú ẹ ti Ogbeni @ProfOsinbajo dá sí laipe yii ni ṣíṣe atunto àwọn eka ọlọ́pàá SARS to sì rọ àwọn ajafeto ọmọniyan láti ṣèwádìí àwọn esun tí ara ilu fi kan ẹ̀ka ọlọ́pàá náà.
.@ProfOsinbajo bákan náà lai fò tá pé, yọ Oga agba àjò DSS, Lawal Musa Daura.
Igbakeji ààrẹ @ProfOsinbajo tún pàṣẹ fún banki àpapò Nàìjíríà (CBN) láti kó ọ̀pọ̀lọpọ̀ mílíọ̀nù dola sì tà láti mú eto ọ̀rọ̀ ajé Nàìjíríà lọ geere.
.@ProfOsinbajo Ó tún tẹ́wọ́ gba ìlànà eto Ẹ̀kọ́ gbogbo ọmọ lọ ṣe pàtàkì( every child counts)
N-SIP
Ń-Power

Àwọn akẹ́kọ̀ọ́ gboyè níbi ètò ogbin, Eto ikole ìjọba tí ìhà ìwọ-oòrùn-gúúsù tí base de idà àádọ́rin.
Missing some Tweet in this thread?
You can try to force a refresh.

Like this thread? Get email updates or save it to PDF!

Subscribe to YorubaNewsAlert
Profile picture

Get real-time email alerts when new unrolls are available from this author!

This content may be removed anytime!

Twitter may remove this content at anytime, convert it as a PDF, save and print for later use!

Try unrolling a thread yourself!

how to unroll video

1) Follow Thread Reader App on Twitter so you can easily mention us!

2) Go to a Twitter thread (series of Tweets by the same owner) and mention us with a keyword "unroll" @threadreaderapp unroll

You can practice here first or read more on our help page!

Did Thread Reader help you today?

Support us! We are indie developers!


This site is made by just three indie developers on a laptop doing marketing, support and development! Read more about the story.

Become a Premium Member and get exclusive features!

Premium member ($30.00/year)

Too expensive? Make a small donation by buying us coffee ($5) or help with server cost ($10)

Donate via Paypal Become our Patreon

Thank you for your support!